Matiu 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n bi í pé, “Kí ló dé tí o fi ń fi òwe bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀?”

Matiu 13

Matiu 13:9-15