Matiu 1:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Juda bí Peresi ati Sera, ìyá wọn ni Tamari. Peresi bí Hesironi, Hesironi bí Ramu.

4. Ramu bí Aminadabu, Aminadabu bí Naṣoni, Naṣoni bí Salimoni.

5. Salimoni bí Boasi, ìyá Boasi ni Rahabu, Boasi bí Obedi. Ìyá Obedi ni Rutu. Obedi bí Jese.

Matiu 1