Matiu 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Salimoni bí Boasi, ìyá Boasi ni Rahabu, Boasi bí Obedi. Ìyá Obedi ni Rutu. Obedi bí Jese.

Matiu 1

Matiu 1:1-10