Luku 8:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu tún tẹnu mọ́ ọn pé, “Ẹnìkan fọwọ́ kàn mí sẹ́ẹ̀, nítorí mo mọ̀ pé agbára ti ara mi jáde.”

Luku 8

Luku 8:42-47