Luku 8:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu ní, “Ta ni fọwọ́ kàn mí?”Nígbà tí gbogbo wọn sẹ́, Peteru ní, “Ọ̀gá, mélòó-mélòó ni àwọn eniyan tí wọn ń fún ọ, tí wọn ń tì ọ́?”

Luku 8

Luku 8:37-55