Luku 6:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí gbogbo eniyan bá ń ròyìn yín ní rere, ẹ gbé, nítorí bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba wọn ṣe sí àwọn èké wolii.

Luku 6

Luku 6:23-35