Luku 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin tí ẹ yó nisinsinyii, ẹ gbé,nítorí ebi ń bọ̀ wá pa yín.Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń yọ̀ nisinsinyii, ẹ gbé,nítorí ọ̀fọ̀ óo ṣẹ̀ yín, ẹ óo sì sunkún.

Luku 6

Luku 6:18-27