Luku 22:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo sọ fun yín pé n kò tún ní jẹ ẹ́ mọ́ títí di àkókò tí yóo fi ní ìtumọ̀ tí ó pé ní ìjọba Ọlọrun.”

Luku 22

Luku 22:12-18