Luku 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “Ó ti mú mi lọ́kàn pupọ láti jẹ àsè Ìrékọjá yìí pẹlu yín kí n tó jìyà.

Luku 22

Luku 22:10-16