Luku 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá wò wọ́n lójú, ó ní, “Ǹjẹ́ kí ni ìtumọ̀ àkọsílẹ̀ yìí,‘Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀,òun ni ó di òkúta pataki ní igun ilé.’

Luku 20

Luku 20:9-18