Luku 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo pa àwọn alágbàro wọnyi, yóo sì gbé ọgbà rẹ̀ fún àwọn mìíràn láti tọ́jú.”Nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n ní “Ọlọrun má jẹ́!”

Luku 20

Luku 20:13-17