Luku 20:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin yìí tún rán ẹrú mìíràn. Àwọn alágbàro yìí tún lù ú, wọ́n fi àbùkù kàn án, wọ́n bá tún dá òun náà pada ní ọwọ́ òfo.

Luku 20

Luku 20:7-19