Luku 20:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ó rán ẹrú rẹ̀ kan sí àwọn alágbàro náà. Ṣugbọn àwọn alágbàro yìí lù ú, wọ́n bá dá a pada ní ọwọ́ òfo.

Luku 20

Luku 20:8-13