Luku 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tún lọ láti rú ẹbọ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà ninu òfin Oluwa: pẹlu àdàbà meji, tabi ọmọ ẹyẹlé meji.

Luku 2

Luku 2:19-30