Luku 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ ninu òfin Oluwa pé, “Gbogbo àkọ́bí lọkunrin ni a óo pè ní mímọ́ fún Oluwa.”

Luku 2

Luku 2:16-24