Luku 18:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu súnmọ́ etí ìlú Jẹriko, afọ́jú kan wà lẹ́bàá ọ̀nà, ó jókòó, ó ń ṣagbe.

Luku 18

Luku 18:26-43