Luku 18:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ohun tí ó sọ kò yé wọn. Ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ náà sápamọ́ fún wọn. Wọn kò mọ ohun tí ó ń sọ.

Luku 18

Luku 18:26-39