Luku 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu pa òwe kan fún wọn láti kọ́ wọn pé eniyan gbọdọ̀ máa gbadura nígbà gbogbo, láì ṣàárẹ̀.

Luku 18

Luku 18:1-3