Luku 17:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bi í pé, “Níbo ni, Oluwa?”Ó dá wọn lóhùn pé, “Níbi tí òkú ẹran bá wà, níbẹ̀ ni àwọn igún ń péjọ sí.”

Luku 17

Luku 17:34-37