Luku 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun bá dáhùn pé, ‘Ọgọrun-un garawa epo.’ Ó sọ fún un pé, ‘Gba ìwé àkọsílẹ̀ rẹ, tètè jókòó, kọ aadọta.’

Luku 16

Luku 16:5-9