Luku 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ó bá pe ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn tí ó jẹ ọ̀gá rẹ̀ ní gbèsè. Ó bi ekinni pé, ‘Èló ni o jẹ ọ̀gá mi?’

Luku 16

Luku 16:1-15