Luku 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa iranṣẹ náà sọ fún un pé, ‘Lọ sí ọ̀nà oko, kí o bẹ àwọn ẹni tí o bá rí, kí wọ́n wọlé wá, kí inú ilé mi baà kún.

Luku 14

Luku 14:19-33