Luku 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí iranṣẹ náà ti ṣe bẹ́ẹ̀ tán, ó ní, ‘Alàgbà, a ti ṣe bí o ti pàṣẹ, sibẹ àyè tún kù.’

Luku 14

Luku 14:18-29