Luku 12:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin náà, ẹ wà ní ìmúrasílẹ̀, nítorí ní àkókò tí ẹ kò nírètí ni Ọmọ-Eniyan yóo dé.”

Luku 12

Luku 12:37-46