Luku 12:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ mọ èyí pé bí ó bá jẹ́ pé baálé ilé mọ àkókò tí olè yóo dé, kò ní fi ilé rẹ̀ sílẹ̀ kí olè kó o.

Luku 12

Luku 12:32-46