Luku 10:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń lọ ninu ìrìn àjò wọn, Jesu wọ inú abúlé kan. Obinrin kan tí ń jẹ́ Mata bá gbà á lálejò.

Luku 10

Luku 10:30-42