Luku 10:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Amòfin náà dáhùn pé, “Ẹni tí ó ṣàánú fún un ni.”Jesu sọ fún un pé, “Ìwọ náà lọ ṣe bẹ́ẹ̀ gan-an.”

Luku 10

Luku 10:29-42