Luku 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò ní ọmọ, nítorí pé Elisabẹti yàgàn. Àwọn mejeeji ni wọ́n sì ti di arúgbó.

Luku 1

Luku 1:1-10