Luku 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mejeeji ń rìn déédé níwájú Ọlọrun, wọ́n ń pa gbogbo àwọn àṣẹ ati ìlànà Oluwa mọ́ láì kùnà.

Luku 1

Luku 1:4-13