Luku 1:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kígbe sókè, ó ní, “Ibukun Ọlọrun wà lórí rẹ pupọ láàrin àwọn obinrin. Ibukun Ọlọrun sì wà lórí ọmọ inú rẹ.

Luku 1

Luku 1:41-52