Luku 1:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Elisabẹti ti gbọ́ ohùn Maria, bẹ́ẹ̀ ni ọlẹ̀ sọ ninu rẹ̀; Elisabẹti sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́.

Luku 1

Luku 1:33-42