Lefitiku 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó mú àwọn igẹ̀ ẹran náà ati itan ọ̀tún wọn, ó fì wọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífì níwájú OLUWA, bí Mose ti pa á láṣẹ.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:14-23