Lefitiku 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó gbogbo ọ̀rá náà lé orí igẹ̀ ẹran náà; ó sun ún lórí pẹpẹ.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:10-21