Lefitiku 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fọ àwọn nǹkan inú rẹ̀, ati ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì sun wọ́n papọ̀ pẹlu ẹbọ sísun lórí pẹpẹ.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:4-19