Lefitiku 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé ẹran ẹbọ sísun tí wọ́n ti gé sí wẹ́wẹ́, ati orí rẹ̀ tọ̀ ọ́ lọ, ó sì sun wọ́n lórí pẹpẹ.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:5-18