Lefitiku 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Mose fa àgbò ẹbọ sísun kalẹ̀, Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin sì gbé ọwọ́ wọn lé e lórí.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:14-28