Lefitiku 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó dáná sun ara ẹran akọ mààlúù náà, ati awọ rẹ̀, ati ìgbẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn ibùdó náà, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:15-19