Lefitiku 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mààlúù ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ jáde, Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin gbé ọwọ́ lé e lórí.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:13-20