Lefitiku 8:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose kó àwọn ọmọ Aaroni, ó wọ̀ wọ́n lẹ́wù, ó sì dì wọ́n ní àmùrè, ó dé wọn ní fìlà, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:3-20