Lefitiku 4:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo sì ti ìka bọ inú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, yóo fi sí ara ìwo pẹpẹ ẹbọ sísun, yóo sì da ẹ̀jẹ̀ yòókù sí ìdí pẹpẹ.

Lefitiku 4

Lefitiku 4:22-35