Lefitiku 4:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo gbé ọwọ́ lé orí ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ yìí, yóo sì pa á, níbi tí wọ́n ti ń rú ẹbọ sísun.

Lefitiku 4

Lefitiku 4:19-35