Lefitiku 25:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, iranṣẹ mi ni wọ́n, tí mo kó jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti, ẹnìkan kò gbọdọ̀ tà wọ́n lẹ́rú.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:34-43