Lefitiku 25:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni yóo kúrò lọ́dọ̀ rẹ, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀, yóo pada sí ọ̀dọ̀ àwọn eniyan rẹ̀, ati sórí ilẹ̀ ìní àwọn baba rẹ̀.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:37-50