Lefitiku 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún mẹfa ni kí ẹ máa fi gbin èso sinu oko yín, ọdún mẹfa náà sì ni kí ẹ máa fi tọ́jú ọgbà àjàrà yín, tí ẹ óo sì máa fi kórè èso rẹ̀.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:1-9