Lefitiku 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti jẹ gbogbo rẹ̀ tán ní ọjọ́ kan náà, kò gbọdọ̀ kù di òwúrọ̀ ọjọ́ keji. Èmi ni OLUWA.

Lefitiku 22

Lefitiku 22:22-33