Lefitiku 22:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ bá sì ń rú ẹbọ ọpẹ́ sí OLUWA, ẹ gbọdọ̀ rú u ní ọ̀nà tí yóo fi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà.

Lefitiku 22

Lefitiku 22:20-33