Lefitiku 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò sì gbọdọ̀ kọ́ àṣà àwọn orílẹ̀-èdè tí n óo lé jáde fun yín, nítorí pé tìtorí gbogbo ohun tí wọn ń ṣe wọnyi ni mo fi kórìíra wọn.

Lefitiku 20

Lefitiku 20:20-27