Lefitiku 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ gbọdọ̀ kíyèsí gbogbo àwọn ìlànà mi ati àwọn òfin mi, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́, kí ilẹ̀ tí mò ń ko yín lọ má baà tì yín jáde.

Lefitiku 20

Lefitiku 20:17-23