Lefitiku 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ gbẹ̀san, tabi kí ẹ di ọmọ eniyan yín sinu, ṣugbọn ẹ níláti fẹ́ràn ọmọnikeji yín gẹ́gẹ́ bí ara yín. Èmi ni OLUWA.

Lefitiku 19

Lefitiku 19:10-21