Lefitiku 19:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ di arakunrin yín sinu, ṣugbọn ẹ gbọdọ̀ máa sọ àsọyé pẹlu aládùúgbò yín, kí ẹ má baà gbẹ̀ṣẹ̀ nítorí tirẹ̀.

Lefitiku 19

Lefitiku 19:11-25